Gospel Music

Korin Si Oluwa (Sing To The Lord) – Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo

Korin Si Oluwa (Sing To The Lord) - Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo

Debra Crown-Olu UK Based Nigerian Gospel Minister, aka Evangelist Debby Mojisola Adedapo-Olukayode releases another powerful brand new single titled “Korin Si Oluwa” which means “Sing Unto The Lord” and she features Nigerian Gospel Special Alujo Minister, Laolu Gbenjo.

This is their first collaborative effort, as they offer deep praise to God on this melodious alujo-tempo. Laced with essential of Africa percussion.

Telegram

Korin Si Oluwa” is a Victory Praise to almighty God, declaring His awesomeness, strange works, strange acts and His mighty hands which gives us victory over all situations. According to Exodus 15 and Psalm 3:3 (Ekisodu 15). It is sang in Yoruba Language.

Korin Si Oluwa was produced by Tobass Adolphus Records.

Stream & Download Audio Below; 

 

 

 

 

Lyrics: Korin Si Oluwa By Debra Crown-Olu Ft. Laolu Gbenjo

Chorus:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

OLUWA li agbara ati orin mi,
on li o si di ìgbala mi:
eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;
Kabioyesi mo se iba re
Emi o kọrin si OLUWA,

Chorus:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

Oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
olugbe ori mi soke.
Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa,
o si gbohùn mi lati òke mimọ́ rẹ̀ wá.
Emi o kọrin si OLUWA,
Oba to ‘n be ninu orun
Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.

O ran omo ni se fayati
Responses: gbega mi o le sai gbega titi lai.
You are bigger than the biggest
Responses: gbega mi o le sai gbega titi lai.
Olowogbogboro ti ‘n gba omo re lofin
Responses: gbega mi o le sai gbega titi lai.

A se kabiesi re eladumare tewogbope (Interlude (Omo egbala gbo in so ke).
Oba to ti wa o, k’ aye to wati si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo
Mo ni, Oluwa n’ be bi ti ati Jo
Response: A wa la o sin baba bi ta ti jo.

Bridge:
Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ̀.
ọwọ́ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
ọwọ́ ọtún rẹ fọ́ ọtá tútu.
Emi o kọrin si OLUWA,

Mo korin hallelujah
Mo ke hallelujah
Ona to di ti la o
Oluwa la ona ni bi to ko so na
Ona to di ti la o
Ogo oluwa won la ye mi

 

mm
the authorAyodele Smart
King Ayo Smart is a Social Media Strategist & a Minister Of The Gospel! I'm also a widely online publisher, leading the revolution in Gospel Media #KingdomBlogger

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.